The need to reduce stress makes laughing a worthy trade. Enjoy yourself.
akinbo a. a. cornerstone
Compilation to date of one over a thousand of Onifete. Published on the
www.takingitglobal.com platform for fun.
Enjoy it.
ISSN: 9Geria2Much!
===================
onifete ko lo kiirun lori express;
onifete ko lo tamba legebe transformer;
onifete ko lo fi ejo se tie;
onifete ko lo fi indomie fa gen;
onifete ko lo fi eja kika s'oruka;
Onifete ko fi generator se pendant;
onifete ko fi atagigun kun powder;
Onifete ko fi transformer se teddybear;
onifete ko lo mop lagoon front;
onifete ko fi generator se pendant;
onifete ko fi omo-odo lu gangan;
onifete ko lo lap maalu;
Onifete ko lo saluwala lori express;
onifete kolo fi atagigun she eye shadow;
onifete kolofi ATM gbowo ninu kolo now;
onifete bere ona lowo alangba;
onifete she pedicure fun lion;
onifete kofi sandpaper se toilet roll?
Onifete kofi superglue se eyedrop;
onifete ko lofi Obama pe Osama;
Onifete ko fi Clifford Orji se tenant
onifete ko gbe maalu wo BRT;
Onifete ko se Party ni BRT Lane;
oni fe fi polybag she condom;
Onifete ko fi acid mu Garri;
Onifete ko lo gbayawo Tompolo;
Onifete ko fi knockout se cigar;
Onifete ko ro Petrol sinu lantern;
Onifete ko fi Jik mu gari.
Onifete ko diju gbadura fun were;
Onifete ko lo dobale lori 3rd mainland;
Onifete ko lo fi poo mugaari;
onifete ko lo ka dollar laarin eko idumota;
onifete ko lo fi omi isanwo tanba;
onifete ko lo ewe wereke se kankan;
onifete ko diju gbadura fun were;
Onifete kolo ya foto fun eleha;
Onifete ko fi peppersoup tanba;
Onifete ko fi omolanke tow trailer;
Onifete ko ma speak in tongues ni Mecca;
Onifete ko fi snow shower;
Onifeki ki Shooting Stars ra Lionel Messi
Oni fe gbe Okada de China;
Great Ife Minds...
onifete ko fi Oduduwa se osuka ru Amphi.
You want to add yours? You are welcome.
Translated version from Yoruba to English, out soon.